1 Kronika 16:41 OYCB

[41] Pẹ̀lú wọn ni Hemani àti Jedutuni àti ìyókù tí a mú àti yàn nípasẹ̀ orúkọ láti fi ọpẹ́ fún OLÚWA, nítorí tí ìfẹ́ rẹ̀ dúró títí láéláé

About this translation

Life Bible app icon
Get the Life Bible app Read offline, sync highlights and notes, and study with your library on any device.