2 Kronika 3:7 OYCB

[7] Ó tẹ́ àjà ilé náà pẹ̀lú ìtí igi àti ìlẹ̀kùn ògiri àti àwọn ìlẹ̀kùn ilé OLÚWA pẹ̀lú wúrà, ó sì gbẹ́ àwòrán kérúbù sára ògiri.

About this translation

Life Bible app icon
Get the Life Bible app Read offline, sync highlights and notes, and study with your library on any device.